-
Jẹ́nẹ́sísì 2:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Ọlọ́run wá bù kún ọjọ́ keje, ó sì yà á sí mímọ́, torí ọjọ́ yẹn ni Ọlọ́run bẹ̀rẹ̀ sí í sinmi lẹ́yìn gbogbo ohun tó ti dá, ìyẹn gbogbo ohun tó ní lọ́kàn.
-