Sáàmù 97:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Kí ojú ti gbogbo àwọn tó ń sin ère gbígbẹ́,+Àwọn tó ń fi àwọn ọlọ́run asán+ wọn yangàn. Ẹ forí balẹ̀ fún un,* gbogbo ẹ̀yin ọlọ́run.+ Àìsáyà 44:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ta ló máa ṣe ọlọ́run tàbí kó ṣe ère onírin* Tí kò lè ṣàǹfààní rárá?+
7 Kí ojú ti gbogbo àwọn tó ń sin ère gbígbẹ́,+Àwọn tó ń fi àwọn ọlọ́run asán+ wọn yangàn. Ẹ forí balẹ̀ fún un,* gbogbo ẹ̀yin ọlọ́run.+