1 Kíróníkà 16:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Gbogbo ọlọ́run àwọn èèyàn jẹ́ ọlọ́run asán,+Àmọ́ Jèhófà ló dá ọ̀run.+ 1 Kọ́ríńtì 8:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ní báyìí, ní ti jíjẹ oúnjẹ tí wọ́n fi rúbọ sí òrìṣà, a mọ̀ pé òrìṣà kò jẹ́ nǹkan kan+ nínú ayé àti pé kò sí Ọlọ́run míì àfi ọ̀kan ṣoṣo.+
4 Ní báyìí, ní ti jíjẹ oúnjẹ tí wọ́n fi rúbọ sí òrìṣà, a mọ̀ pé òrìṣà kò jẹ́ nǹkan kan+ nínú ayé àti pé kò sí Ọlọ́run míì àfi ọ̀kan ṣoṣo.+