Sáàmù 29:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ẹ fún Jèhófà ní ògo tí ó yẹ orúkọ rẹ̀. Ẹ forí balẹ̀ fún* Jèhófà nínú aṣọ ọ̀ṣọ́ mímọ́.* Sáàmù 72:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Kí á yin orúkọ rẹ̀ ológo títí láé,+Kí ògo rẹ̀ sì kún gbogbo ayé.+ Àmín àti Àmín.