Sáàmù 9:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Yóò fi òdodo ṣe ìdájọ́ ilẹ̀ ayé tí à ń gbé;*+Yóò dá ẹjọ́ òdodo fún àwọn orílẹ̀-èdè.+ Ìṣe 17:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Torí ó ti dá ọjọ́ kan tó máa fi òdodo ṣèdájọ́ + ayé láti ọwọ́ ọkùnrin kan tó ti yàn, ó sì ti pèsè ẹ̀rí tó dájú fún gbogbo èèyàn bó ṣe jí i dìde kúrò nínú ikú.”+
31 Torí ó ti dá ọjọ́ kan tó máa fi òdodo ṣèdájọ́ + ayé láti ọwọ́ ọkùnrin kan tó ti yàn, ó sì ti pèsè ẹ̀rí tó dájú fún gbogbo èèyàn bó ṣe jí i dìde kúrò nínú ikú.”+