- 
	                        
            
            Sáàmù 93:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        93 Jèhófà ti di Ọba!+ Ó gbé ọlá ńlá wọ̀ bí aṣọ; Jèhófà gbé agbára wọ̀; Ó fi di ara rẹ̀ bí àmùrè. 
 
- 
                                        
93 Jèhófà ti di Ọba!+
Ó gbé ọlá ńlá wọ̀ bí aṣọ;
Jèhófà gbé agbára wọ̀;
Ó fi di ara rẹ̀ bí àmùrè.