-
1 Pétérù 1:6, 7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Ẹ̀ ń yọ̀ gidigidi nítorí èyí, bó tiẹ̀ jẹ́ pé fún ìgbà díẹ̀, ó lè pọn dandan kí oríṣiríṣi àdánwò kó ìdààmú bá yín,+ 7 kí ìgbàgbọ́ yín tí a dán wò+ ní ti bó ṣe jẹ́ ojúlówó tó, èyí tó níye lórí gidigidi ju wúrà tó máa ń ṣègbé láìka pé a fi iná dá an wò* sí, lè jẹ́ orísun ìyìn àti ògo àti ọlá nígbà ìfihàn Jésù Kristi.+
-