Ìṣe 7:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 ó gbà á nínú gbogbo ìpọ́njú rẹ̀, ó ṣe ojúure sí i, ó sì fún un ní ọgbọ́n níwájú Fáráò ọba Íjíbítì. Ó yàn án láti ṣàkóso Íjíbítì àti gbogbo ilé rẹ̀.+
10 ó gbà á nínú gbogbo ìpọ́njú rẹ̀, ó ṣe ojúure sí i, ó sì fún un ní ọgbọ́n níwájú Fáráò ọba Íjíbítì. Ó yàn án láti ṣàkóso Íjíbítì àti gbogbo ilé rẹ̀.+