-
Ẹ́kísódù 1:8, 9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Nígbà tó yá, ọba tuntun tí kò mọ Jósẹ́fù jẹ ní Íjíbítì. 9 Ó sọ fún àwọn èèyàn rẹ̀ pé: “Ẹ wò ó! Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pọ̀ jù wá lọ, wọ́n sì tún lágbára jù wá lọ.+
-