Sáàmù 73:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Bí ọ̀rọ̀ àwọn ẹni burúkú ṣe rí nìyí, àwọn tí gbogbo nǹkan dẹrùn fún.+ Wọ́n ń kó ọrọ̀ jọ ṣáá.+