Sáàmù 106:43 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 43 Ọ̀pọ̀ ìgbà ló gbà wọ́n sílẹ̀,+Àmọ́ wọ́n á ṣọ̀tẹ̀, wọ́n á sì ṣàìgbọràn,+A ó sì rẹ̀ wọ́n sílẹ̀ nítorí àṣìṣe wọn.+ Ìdárò 3:42 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 42 “A ti dẹ́ṣẹ̀, a ti ṣọ̀tẹ̀,+ ìwọ kò sì tíì dárí jì wá.+
43 Ọ̀pọ̀ ìgbà ló gbà wọ́n sílẹ̀,+Àmọ́ wọ́n á ṣọ̀tẹ̀, wọ́n á sì ṣàìgbọràn,+A ó sì rẹ̀ wọ́n sílẹ̀ nítorí àṣìṣe wọn.+