- 
	                        
            
            Sáàmù 20:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        6 Mo ti wá mọ̀ pé Jèhófà ń gba ẹni àmì òróró rẹ̀ sílẹ̀.+ 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Sáàmù 60:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        5 Kí a lè gba àwọn olùfẹ́ rẹ sílẹ̀, Fi ọwọ́ ọ̀tún rẹ gbà wá sílẹ̀, kí o sì dá wa lóhùn.+ 
 
-