- 
	                        
            
            Sáàmù 55:12-14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        Kì í ṣe elénìní ló dìde sí mi; Tó bá jẹ́ bẹ́ẹ̀, mi ò bá sá pa mọ́ fún un. 14 Ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́ ni wá tẹ́lẹ̀, a sì gbádùn ọ̀rẹ́ wa; A máa ń bá ọ̀pọ̀ èèyàn rìn lọ sí ilé Ọlọ́run. 
 
-