Sáàmù 68:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹ kọrin sí Ọlọ́run; ẹ fi orin yin* orúkọ rẹ̀.+ Ẹ kọrin sí Ẹni tó ń la àwọn aṣálẹ̀ tó tẹ́jú* kọjá. Jáà* ni orúkọ rẹ̀!+ Ẹ máa yọ̀ níwájú rẹ̀! Sáàmù 113:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 113 Ẹ yin Jáà!* Ẹ mú ìyìn wá, ẹ̀yin ìránṣẹ́ Jèhófà,Ẹ yin orúkọ Jèhófà. Ìfihàn 19:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Lẹ́yìn èyí, mo gbọ́ ohun kan ní ọ̀run tó dún bí ohùn àwọn tó pọ̀ gan-an. Wọ́n sọ pé: “Ẹ yin Jáà!*+ Ti Ọlọ́run wa ni ìgbàlà àti ògo àti agbára,
4 Ẹ kọrin sí Ọlọ́run; ẹ fi orin yin* orúkọ rẹ̀.+ Ẹ kọrin sí Ẹni tó ń la àwọn aṣálẹ̀ tó tẹ́jú* kọjá. Jáà* ni orúkọ rẹ̀!+ Ẹ máa yọ̀ níwájú rẹ̀!
19 Lẹ́yìn èyí, mo gbọ́ ohun kan ní ọ̀run tó dún bí ohùn àwọn tó pọ̀ gan-an. Wọ́n sọ pé: “Ẹ yin Jáà!*+ Ti Ọlọ́run wa ni ìgbàlà àti ògo àti agbára,