Sáàmù 9:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Jèhófà, màá fi gbogbo ọkàn mi yìn ọ́;Màá sọ nípa gbogbo iṣẹ́ àgbàyanu rẹ.+