Sáàmù 77:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Màá ṣe àṣàrò lórí gbogbo iṣẹ́ rẹ,Màá sì ronú jinlẹ̀ nípa àwọn ohun tí o ṣe.+ Sáàmù 143:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Mo rántí àwọn ọjọ́ àtijọ́;Mo ṣe àṣàrò lórí gbogbo iṣẹ́ rẹ;+Ó ń yá mi lára láti máa ronú lórí* iṣẹ́ ọwọ́ rẹ.
5 Mo rántí àwọn ọjọ́ àtijọ́;Mo ṣe àṣàrò lórí gbogbo iṣẹ́ rẹ;+Ó ń yá mi lára láti máa ronú lórí* iṣẹ́ ọwọ́ rẹ.