Sáàmù 44:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ọwọ́ rẹ ni o fi lé àwọn orílẹ̀-èdè jáde,+O sì mú kí àwọn baba ńlá wa máa gbé níbẹ̀.+ O fọ́ àwọn orílẹ̀-èdè, o sì lé wọn jáde.+ Sáàmù 105:44 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 44 Ó fún wọn ní ilẹ̀ àwọn orílẹ̀-èdè;+Wọ́n jogún ohun tí àwọn míì ti ṣiṣẹ́ kára láti mú jáde,+
2 Ọwọ́ rẹ ni o fi lé àwọn orílẹ̀-èdè jáde,+O sì mú kí àwọn baba ńlá wa máa gbé níbẹ̀.+ O fọ́ àwọn orílẹ̀-èdè, o sì lé wọn jáde.+