- 
	                        
            
            1 Kíróníkà 16:36Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        Gbogbo èèyàn sì sọ pé, “Àmín!”* wọ́n sì yin Jèhófà. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            1 Kíróníkà 29:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        10 Nígbà náà, Dáfídì yin Jèhófà lójú gbogbo ìjọ náà. Dáfídì sọ pé: “Ìyìn ni fún ọ, Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì baba wa, títí láé àti láéláé.* 
 
-