- 
	                        
            
            2 Kọ́ríńtì 4:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        13 Ní báyìí, torí a ní ẹ̀mí ìgbàgbọ́ kan náà, irú èyí tí a kọ nípa rẹ̀ pé: “Mo ní ìgbàgbọ́, torí náà mo sọ̀rọ̀”;+ àwa náà ní ìgbàgbọ́, torí náà a sọ̀rọ̀, 
 
-