Róòmù 15:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àti pé: “Ẹ yin Jèhófà,* gbogbo ẹ̀yin orílẹ̀-èdè, kí gbogbo àwọn èèyàn sì yìn ín.”+