Mátíù 26:52, 53 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 52 Jésù wá sọ fún un pé: “Dá idà rẹ pa dà sí àyè rẹ̀,+ torí gbogbo àwọn tó bá yọ idà máa ṣègbé nípasẹ̀ idà.+ 53 Àbí o rò pé mi ò lè bẹ Baba mi pé kó fún mi ní àwọn áńgẹ́lì tó ju líjíónì méjìlá (12) lọ ní ìṣẹ́jú yìí?+
52 Jésù wá sọ fún un pé: “Dá idà rẹ pa dà sí àyè rẹ̀,+ torí gbogbo àwọn tó bá yọ idà máa ṣègbé nípasẹ̀ idà.+ 53 Àbí o rò pé mi ò lè bẹ Baba mi pé kó fún mi ní àwọn áńgẹ́lì tó ju líjíónì méjìlá (12) lọ ní ìṣẹ́jú yìí?+