Sáàmù 112:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 112 Ẹ yin Jáà!*+ א [Áléfì] Aláyọ̀ ni ẹni tó bẹ̀rù Jèhófà,+ב [Bétì] Tó sì fẹ́ràn àwọn àṣẹ rẹ̀ gan-an.+
112 Ẹ yin Jáà!*+ א [Áléfì] Aláyọ̀ ni ẹni tó bẹ̀rù Jèhófà,+ב [Bétì] Tó sì fẹ́ràn àwọn àṣẹ rẹ̀ gan-an.+