Sáàmù 51:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 51 Ọlọ́run, ṣojú rere sí mi, nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀.+ Nu àwọn àṣìṣe mi kúrò nítorí ọ̀pọ̀ àánú rẹ.+ Sáàmù 103:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Bí bàbá ṣe ń ṣàánú àwọn ọmọ rẹ̀,Bẹ́ẹ̀ ni Jèhófà ń ṣàánú àwọn tó bẹ̀rù rẹ̀.+ Sáàmù 119:116 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 116 Tì mí lẹ́yìn bí o ti ṣèlérí,*+Kí n lè máa wà láàyè;Má ṣe jẹ́ kí ìrètí mi já sí asán.*+ Dáníẹ́lì 9:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ọlọ́run mi, tẹ́tí sílẹ̀, kí o sì gbọ́! La ojú rẹ, kí o sì rí ìyà tó ń jẹ wá àti bí ìlú tí a fi orúkọ rẹ pè ṣe di ahoro; kì í ṣe torí àwọn ìṣe òdodo wa la ṣe ń bẹ̀ ọ́, torí àánú rẹ tó pọ̀ ni.+ Lúùkù 1:50 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 50 àti pé láti ìran dé ìran, ó ń ṣàánú àwọn tó bẹ̀rù rẹ̀.+
51 Ọlọ́run, ṣojú rere sí mi, nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀.+ Nu àwọn àṣìṣe mi kúrò nítorí ọ̀pọ̀ àánú rẹ.+
18 Ọlọ́run mi, tẹ́tí sílẹ̀, kí o sì gbọ́! La ojú rẹ, kí o sì rí ìyà tó ń jẹ wá àti bí ìlú tí a fi orúkọ rẹ pè ṣe di ahoro; kì í ṣe torí àwọn ìṣe òdodo wa la ṣe ń bẹ̀ ọ́, torí àánú rẹ tó pọ̀ ni.+