Àìsáyà 45:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Gbogbo ọmọ* Ísírẹ́lì máa fi hàn pé àwọn ṣe ohun tó tọ́ nínú Jèhófà,+Òun ni wọ́n á sì máa fi yangàn.’”
25 Gbogbo ọmọ* Ísírẹ́lì máa fi hàn pé àwọn ṣe ohun tó tọ́ nínú Jèhófà,+Òun ni wọ́n á sì máa fi yangàn.’”