-
Sáàmù 119:88Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
88 Mú kí n máa wà láàyè nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀,
Kí n lè máa pa àwọn ìránnilétí tí o sọ mọ́.