1 Àwọn Ọba 18:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Lẹ́yìn náà Èlíjà wá bá gbogbo àwọn èèyàn náà, ó sì sọ pé: “Ìgbà wo lẹ máa ṣiyèméjì* dà?+ Tó bá jẹ́ pé Jèhófà ni Ọlọ́run tòótọ́, ẹ tẹ̀ lé e;+ àmọ́ tó bá jẹ́ pé Báálì ni, ẹ tẹ̀ lé e!” Àwọn èèyàn náà kò sì fèsì kankan. Ìfihàn 3:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Àmọ́ torí pé ṣe lo lọ́wọ́ọ́wọ́, tí o ò gbóná,+ tí o ò sì tutù,+ màá pọ̀ ọ́ jáde lẹ́nu mi.
21 Lẹ́yìn náà Èlíjà wá bá gbogbo àwọn èèyàn náà, ó sì sọ pé: “Ìgbà wo lẹ máa ṣiyèméjì* dà?+ Tó bá jẹ́ pé Jèhófà ni Ọlọ́run tòótọ́, ẹ tẹ̀ lé e;+ àmọ́ tó bá jẹ́ pé Báálì ni, ẹ tẹ̀ lé e!” Àwọn èèyàn náà kò sì fèsì kankan.