2 Àwọn Ọba 10:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ló bá sọ pé: “Bá mi ká lọ, kí o sì rí bí mi ò ṣe fàyè gba bíbá Jèhófà díje.”*+ Torí náà, wọ́n mú un wọnú kẹ́kẹ́ ogun rẹ̀, wọ́n sì jọ ń lọ. Sáàmù 69:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ìtara ilé rẹ ti gbà mí lọ́kàn,+Ẹ̀gàn ẹnu àwọn tó ń pẹ̀gàn rẹ sì ti wá sórí mi.+ Jòhánù 2:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ rántí pé a ti kọ ọ́ pé: “Ìtara ilé rẹ máa gbà mí lọ́kàn.”+
16 Ló bá sọ pé: “Bá mi ká lọ, kí o sì rí bí mi ò ṣe fàyè gba bíbá Jèhófà díje.”*+ Torí náà, wọ́n mú un wọnú kẹ́kẹ́ ogun rẹ̀, wọ́n sì jọ ń lọ.