- 
	                        
            
            Sáàmù 84:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        7 Wọ́n á máa ti inú agbára bọ́ sínú agbára;+ Kálukú wọn ń wá síwájú Ọlọ́run ní Síónì. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Sáàmù 100:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        Ẹ fi ọpẹ́ fún un; ẹ yin orúkọ rẹ̀.+ 
 
-