Sáàmù 119:82 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 82 Ojú mi fẹ́ máa rí ọ̀rọ̀ rẹ+Nígbà tí mo béèrè pé: “Ìgbà wo lo máa tù mí nínú?”+ Sáàmù 130:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Mò* ń retí Jèhófà,+Ju bí àwọn olùṣọ́ ṣe ń retí pé kí ilẹ̀ mọ́,+Àní, ju bí àwọn olùṣọ́ ṣe ń retí pé kí ilẹ̀ mọ́.
6 Mò* ń retí Jèhófà,+Ju bí àwọn olùṣọ́ ṣe ń retí pé kí ilẹ̀ mọ́,+Àní, ju bí àwọn olùṣọ́ ṣe ń retí pé kí ilẹ̀ mọ́.