Ìdárò 3:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Jèhófà jẹ́ ẹni rere sí ẹni tó gbẹ́kẹ̀ lé e,+ ìyẹn ẹni* tó ń wá a.+ Míkà 7:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àmọ́ ní tèmi, èmi yóò máa retí Jèhófà.+ Màá dúró* de Ọlọ́run ìgbàlà mi.+ Ọlọ́run mi yóò gbọ́ mi.+