Sáàmù 3:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Jèhófà, kí nìdí tí àwọn ọ̀tá mi fi pọ̀ tó báyìí?+ Kí nìdí tí ọ̀pọ̀ èèyàn fi ń dìde sí mi?+ Sáàmù 22:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Nítorí àwọn ajá yí mi ká;+Wọ́n ká mi mọ́ bí ìgbà tí àwọn aṣebi bá káni mọ́,+Wọ́n wà níbi ọwọ́ àti ẹsẹ̀ mi bíi kìnnìún.+
16 Nítorí àwọn ajá yí mi ká;+Wọ́n ká mi mọ́ bí ìgbà tí àwọn aṣebi bá káni mọ́,+Wọ́n wà níbi ọwọ́ àti ẹsẹ̀ mi bíi kìnnìún.+