-
Sáàmù 56:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
56 Ṣojú rere sí mi, Ọlọ́run, nítorí ẹni kíkú ń gbéjà kò mí.*
Láti àárọ̀ ṣúlẹ̀, wọ́n ń bá mi jà, wọ́n sì ń ni mí lára.