-
Àìsáyà 9:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 O ti sọ orílẹ̀-èdè náà di púpọ̀;
O ti mú kó máa yọ̀ gidigidi.
Wọ́n ń yọ̀ níwájú rẹ
Bí àwọn èèyàn ṣe ń yọ̀ nígbà ìkórè,
Bí àwọn tó ń fayọ̀ pín ẹrù ogun.
-