2 Sámúẹ́lì 22:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Ìrànlọ́wọ́ rẹ ni mo fi lè gbéjà ko àwọn jàǹdùkú;*Agbára Ọlọ́run ni mo fi lè gun ògiri.+ Fílípì 4:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Mo ní okun láti ṣe ohun gbogbo nípasẹ̀ ẹni tó ń fún mi lágbára.+