Oníwàásù 5:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ohun tí mo rí pé ó dára tí ó sì tọ́ ni pé: kéèyàn máa jẹ, kó máa mu, kó sì jẹ ìgbádùn gbogbo iṣẹ́ àṣekára+ tó fi gbogbo agbára rẹ̀ ṣe lábẹ́ ọ̀run* láàárín ọjọ́ díẹ̀ tí Ọlọ́run tòótọ́ fún un, nítorí èrè* rẹ̀ nìyẹn.+ Àìsáyà 65:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Wọn ò ní kọ́lé fún ẹlòmíì gbé,Wọn ò sì ní gbìn fún ẹlòmíì jẹ. Torí pé ọjọ́ àwọn èèyàn mi máa dà bí ọjọ́ igi,+Àwọn àyànfẹ́ mi sì máa gbádùn iṣẹ́ ọwọ́ wọn dé ẹ̀kúnrẹ́rẹ́.
18 Ohun tí mo rí pé ó dára tí ó sì tọ́ ni pé: kéèyàn máa jẹ, kó máa mu, kó sì jẹ ìgbádùn gbogbo iṣẹ́ àṣekára+ tó fi gbogbo agbára rẹ̀ ṣe lábẹ́ ọ̀run* láàárín ọjọ́ díẹ̀ tí Ọlọ́run tòótọ́ fún un, nítorí èrè* rẹ̀ nìyẹn.+
22 Wọn ò ní kọ́lé fún ẹlòmíì gbé,Wọn ò sì ní gbìn fún ẹlòmíì jẹ. Torí pé ọjọ́ àwọn èèyàn mi máa dà bí ọjọ́ igi,+Àwọn àyànfẹ́ mi sì máa gbádùn iṣẹ́ ọwọ́ wọn dé ẹ̀kúnrẹ́rẹ́.