Sáàmù 127:4, 5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Bí ọfà ní ọwọ́ alágbára ọkùnrin,Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ téèyàn bí nígbà ọ̀dọ́.+ 5 Aláyọ̀ ni ọkùnrin tó fi wọ́n kún apó rẹ̀.+ Ojú kò ní tì wọ́n,Nítorí wọ́n á bá àwọn ọ̀tá sọ̀rọ̀ ní ẹnubodè ìlú.
4 Bí ọfà ní ọwọ́ alágbára ọkùnrin,Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ téèyàn bí nígbà ọ̀dọ́.+ 5 Aláyọ̀ ni ọkùnrin tó fi wọ́n kún apó rẹ̀.+ Ojú kò ní tì wọ́n,Nítorí wọ́n á bá àwọn ọ̀tá sọ̀rọ̀ ní ẹnubodè ìlú.