- 
	                        
            
            Ẹ́kísódù 5:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        6 Ọjọ́ yẹn gan-an ni Fáráò pàṣẹ fún àwọn tó ń kó wọn ṣiṣẹ́ àti àwọn olórí wọn pé: 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Ẹ́kísódù 5:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        9 Ẹ jẹ́ kí wọ́n túbọ̀ ṣiṣẹ́ kára, ẹ sì jẹ́ kí ọwọ́ wọn dí kí wọ́n má bàa fetí sí irọ́.” 
 
-