Ìdárò 1:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Júdà ti lọ sí ìgbèkùn+ nínú ìpọ́njú, ó sì ń ṣe ẹrú nínú ìnira.+ Ó gbọ́dọ̀ máa gbé láàárín àwọn orílẹ̀-èdè;+ kò rí ibi ìsinmi kankan. Ọwọ́ gbogbo àwọn tó ń ṣe inúnibíni sí i ti tẹ̀ ẹ́ nínú ìdààmú rẹ̀.
3 Júdà ti lọ sí ìgbèkùn+ nínú ìpọ́njú, ó sì ń ṣe ẹrú nínú ìnira.+ Ó gbọ́dọ̀ máa gbé láàárín àwọn orílẹ̀-èdè;+ kò rí ibi ìsinmi kankan. Ọwọ́ gbogbo àwọn tó ń ṣe inúnibíni sí i ti tẹ̀ ẹ́ nínú ìdààmú rẹ̀.