- 
	                        
            
            1 Àwọn Ọba 8:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        17 Ó jẹ́ ìfẹ́ ọkàn Dáfídì bàbá mi pé kí ó kọ́ ilé fún orúkọ Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì.+ 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            1 Kíróníkà 15:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        3 Lẹ́yìn náà, Dáfídì pe gbogbo Ísírẹ́lì jọ sí Jerúsálẹ́mù láti gbé Àpótí Jèhófà wá sí ibi tí ó ti ṣètò sílẹ̀ fún un.+ 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            1 Kíróníkà 15:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        12 ó sọ fún wọn pé: “Ẹ̀yin ni olórí agbo ilé àwọn ọmọ Léfì. Ẹ ya ara yín sí mímọ́, ẹ̀yin àti àwọn arákùnrin yín, kí ẹ sì gbé Àpótí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì wá sí ibi tí mo ti ṣètò sílẹ̀ fún un. 
 
-