1 Kíróníkà 29:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Kí o fún Sólómọ́nì ọmọ mi ní ọkàn pípé,*+ kí ó lè máa pa àwọn àṣẹ rẹ mọ́+ àti àwọn ìránnilétí rẹ pẹ̀lú àwọn ìlànà rẹ, kí ó lè ṣe gbogbo nǹkan yìí, kí ó sì kọ́ tẹ́ńpìlì* tí mo ti pèsè àwọn nǹkan sílẹ̀ fún.”+
19 Kí o fún Sólómọ́nì ọmọ mi ní ọkàn pípé,*+ kí ó lè máa pa àwọn àṣẹ rẹ mọ́+ àti àwọn ìránnilétí rẹ pẹ̀lú àwọn ìlànà rẹ, kí ó lè ṣe gbogbo nǹkan yìí, kí ó sì kọ́ tẹ́ńpìlì* tí mo ti pèsè àwọn nǹkan sílẹ̀ fún.”+