ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 48:2, 3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 Gíga rẹ̀ rẹwà, ayọ̀ gbogbo ayé,+

      Òkè Síónì tó jìnnà réré ní àríwá,

      Ìlú Ọba Títóbi Lọ́lá.+

       3 Nínú àwọn ilé gogoro rẹ̀ tó láàbò,

      Ọlọ́run ti jẹ́ kí a mọ̀ pé òun ni ibi ààbò.*+

  • Sáàmù 78:68
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 68 Àmọ́, ó yan ẹ̀yà Júdà,+

      Òkè Síónì, èyí tí ó nífẹ̀ẹ́.+

  • Hébérù 12:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Àmọ́ ẹ ti sún mọ́ Òkè Síónì+ àti ìlú Ọlọ́run alààyè, Jerúsálẹ́mù ti ọ̀run+ àti ọ̀kẹ́ àìmọye* àwọn áńgẹ́lì

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́