Sáàmù 44:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ọwọ́ rẹ ni o fi lé àwọn orílẹ̀-èdè jáde,+O sì mú kí àwọn baba ńlá wa máa gbé níbẹ̀.+ O fọ́ àwọn orílẹ̀-èdè, o sì lé wọn jáde.+
2 Ọwọ́ rẹ ni o fi lé àwọn orílẹ̀-èdè jáde,+O sì mú kí àwọn baba ńlá wa máa gbé níbẹ̀.+ O fọ́ àwọn orílẹ̀-èdè, o sì lé wọn jáde.+