ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Kíróníkà 7:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Gbogbo àwọn èèyàn Ísírẹ́lì ń wò nígbà tí iná bọ́ sílẹ̀, tí ògo Jèhófà sì bo ilé náà, wọ́n tẹrí ba, wọ́n sì dojú bolẹ̀ lórí ibi tí a fi òkúta tẹ́, wọ́n wólẹ̀, wọ́n sì dúpẹ́ lọ́wọ́ Jèhófà, “nítorí ó jẹ́ ẹni rere; ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ sì wà títí láé.”

  • 2 Kíróníkà 20:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Lẹ́yìn tó fọ̀rọ̀ lọ àwọn èèyàn náà, ó yan àwọn kan láti máa kọrin,+ kí wọ́n sì máa yin Jèhófà nínú aṣọ ọ̀ṣọ́ mímọ́ bí wọ́n ṣe ń lọ níwájú àwọn ọkùnrin tó dìhámọ́ra, wọ́n ní: “Ẹ fi ọpẹ́ fún Jèhófà, nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.”+

  • Sáàmù 106:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 106 Ẹ yin Jáà!*

      Ẹ fi ọpẹ́ fún Jèhófà, nítorí ó jẹ́ ẹni rere;+

      Ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.+

  • Sáàmù 107:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 107 Ẹ fi ọpẹ́ fún Jèhófà, nítorí ó jẹ́ ẹni rere;+

      Ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́