-
Sáàmù 97:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Nítorí pé, ìwọ Jèhófà ni Ẹni Gíga Jù Lọ lórí gbogbo ayé;
O ga fíìfíì ju gbogbo àwọn ọlọ́run yòókù.+
-
-
Dáníẹ́lì 2:47Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
47 Ọba sọ fún Dáníẹ́lì pé: “Lóòótọ́, Ọlọ́run àwọn ọlọ́run àti Olúwa àwọn ọba ni Ọlọ́run yín, ó sì jẹ́ Ẹni tó ń ṣí àwọn àṣírí payá, torí pé o rí àṣírí yìí ṣí payá.”+
-