2 Sámúẹ́lì 22:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 O fún mi ní apata rẹ láti gbà mí là,Ìrẹ̀lẹ̀ rẹ sì sọ mí di ẹni ńlá. + Sáàmù 113:6-8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ó tẹ̀ ba láti wo ọ̀run àti ayé,+ 7 Ó ń gbé aláìní dìde látinú eruku. Ó ń gbé tálákà dìde látorí eérú*+ 8 Kí ó lè mú un jókòó pẹ̀lú àwọn èèyàn pàtàkì,Àwọn ẹni pàtàkì nínú àwọn èèyàn rẹ̀.
6 Ó tẹ̀ ba láti wo ọ̀run àti ayé,+ 7 Ó ń gbé aláìní dìde látinú eruku. Ó ń gbé tálákà dìde látorí eérú*+ 8 Kí ó lè mú un jókòó pẹ̀lú àwọn èèyàn pàtàkì,Àwọn ẹni pàtàkì nínú àwọn èèyàn rẹ̀.