Sáàmù 2:8, 9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Béèrè lọ́wọ́ mi, màá fi àwọn orílẹ̀-èdè ṣe ogún fún ọMàá sì fi gbogbo ìkángun ayé ṣe ohun ìní fún ọ.+ 9 Wàá fi ọ̀pá àṣẹ onírin+ ṣẹ́ wọn,Wàá sì fọ́ wọn túútúú bí ìkòkò amọ̀.”+
8 Béèrè lọ́wọ́ mi, màá fi àwọn orílẹ̀-èdè ṣe ogún fún ọMàá sì fi gbogbo ìkángun ayé ṣe ohun ìní fún ọ.+ 9 Wàá fi ọ̀pá àṣẹ onírin+ ṣẹ́ wọn,Wàá sì fọ́ wọn túútúú bí ìkòkò amọ̀.”+