Àìsáyà 55:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 “Torí bí ọ̀run ṣe ga ju ayé lọ,Bẹ́ẹ̀ ni ọ̀nà mi ga ju ọ̀nà yín,Èrò mi sì ga ju èrò yín.+