Òwe 6:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Nítorí àṣẹ jẹ́ fìtílà,+Òfin jẹ́ ìmọ́lẹ̀,+Àwọn ẹ̀kọ́ inú ìbáwí sì ni ọ̀nà ìyè.+ Jémíìsì 5:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ṣé ẹnikẹ́ni ń ṣàìsàn láàárín yín? Kó pe àwọn alàgbà+ ìjọ, kí wọ́n gbàdúrà lé e lórí, kí wọ́n fi òróró pa á+ ní orúkọ Jèhófà.*
14 Ṣé ẹnikẹ́ni ń ṣàìsàn láàárín yín? Kó pe àwọn alàgbà+ ìjọ, kí wọ́n gbàdúrà lé e lórí, kí wọ́n fi òróró pa á+ ní orúkọ Jèhófà.*