Sáàmù 18:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ó tẹ ọ̀run wálẹ̀ bí ó ṣe ń sọ̀ kalẹ̀.+ Ìṣúdùdù tó kàmàmà sì wà lábẹ́ ẹsẹ̀ rẹ̀.+