-
Lúùkù 10:8, 9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 “Bákan náà, ibikíbi tí ẹ bá ti wọ ìlú kan, tí wọ́n sì gbà yín, ẹ jẹ ohun tí wọ́n bá gbé síwájú yín, 9 kí ẹ wo àwọn aláìsàn tó wà níbẹ̀ sàn, kí ẹ sì sọ fún wọn pé: ‘Ìjọba Ọlọ́run ti sún mọ́ ọ̀dọ̀ yín.’+
-